Take a fresh look at your lifestyle.

Wọ́n sún ọjọ́ Ṣíṣàyẹ̀wò àwọn olùdíje fún ipò ààrẹ PDP,Gómìnà síwájú – NWC

Ìgbìmọ̀ àpapọ̀ ìṣiṣẹ́,  (NWC) ẹgbẹ́ ti sún ọjọ́ ṣíṣàyẹ̀wò àwọn olùdíje fún ipò ààrẹ àti gómìnà  láti ọjọ́ kẹta,oṣù karùn ún sí ọjọ́ kẹrin,oṣù karùn ún. Bakannaa, igbimọ  Alase apapọ ẹgbẹ People's Democratic…

Nàìjíríà, Àwùjọ Àgbáyé, Àwọn mìíràn fọwọ́ sí i láti fòpin sí ìdábẹ́ ọmọbìnrin FGM

Ìjọba Nàìjíríà, àwùjọ àgbáyé, àwọn olùkópa pàtàkì àti àwọn àjọ tí kìí ṣe tìjọba ti pinnu láti fòpin sí Ìdábẹ́ fún ọmọbìnrin ní Nàìjíríà. Wọn ṣe ipinnu naa nibi “Ifilọlẹ  igbesẹ lati fopin si abẹ dida fun ọmọbinrin” ni ilu Abuja.…

Akọ̀wé gbogbogboò Tuntun Fún Ilé-iṣẹ́ Ààbò ṣe àbẹ̀wò sí NAF

Akòwé gbogbogboò tuntun (PermSec),ti ilé-iṣẹ́ ààbò ìjọ̀ba àpapọ̀ (FMoD), Dókítà Ibrahim Kana, mni, ti sọ pé ọ̀kan nínú èròńgbà òhun fún Ilé-iṣẹ́ náà ní láti rí sí gbígbé àwọn òṣìṣẹ́ ológun tó pọ̀ díẹ̀ sí…
button