Take a fresh look at your lifestyle.

Akọrin Nàìjíríà, Tems kọrin pẹ̀lú Future nínú àwo tuntun rẹ̀ tó jáde

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 176

Èwe Olórin Nàìjíríà kan,tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tems ti kọrin nínú àwo orin tuntun tí ó tún jẹ́ ẹlẹẹ̀kẹsàn akọrin  Amẹ́ríkà, Future, tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ ‘I Never Liked You’,

Awo-orin naa ti o ni akọle mẹrindinlogun ni Tems ati ọmọ ilu Kanada, Drake,si jọ kọ  ọkan ninu akole kan ti o jẹ, ‘Wait For You’.

Akọrin  naa pin atọkọ orin ọhun  si oju-iwe Insitagramu rẹ ti o si fi awo orin naa sita ni ọganjọ oru, ọjọ kọkandinlọgbọn, Oṣu Kẹrin, ọdun 2022.

Awọn oṣere bi Kanye West, Gunna, Young thug, Est Gee, ati Kodak Black naa tun kọrin ninu awo-orin ọhun.

Leave A Reply

Your email address will not be published.