Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà dá Ilé-iṣẹ́ Fún Ìṣàkóso Àwọn ohun-ìjà oogun sílẹ̀

Ààrẹ orílẹ̀-ede Nàìjíríà, Mùhámmádù Bùhárí ti fọwọ́sí ìdásílẹ̀ Ilé-iṣẹ́ fún ìṣàkóṣo àwọn ohun-ìjà ogun  kékèré , NCCSALW,t́i ilé-iṣẹ́ oludamọ̀ràn fun aarẹ lori eto  ààbò lOrílẹ̀-ede yii yoo maa sakoso rẹ.…

Covid-19:Ènìyàn méjìdín-lógún míràn tún ti ní ààrùn covid ní orílẹ̀-èdè…

Ilé-iṣẹ́ tó ńmójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,NCDC,ti mu dánilójú pé ènìyàn méjìdín-lógún míràn tùn ti ní ààrùn covid tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí covid-19. Apapọ awọn ti oti ni aarun naa…
button