Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19:Ènìyàn méjìdín-lógún míràn tún ti ní ààrùn covid ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ilé-iṣẹ́ tó ńmójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,NCDC,ti mu dánilójú pé ènìyàn méjìdín-lógún míràn tùn ti ní ààrùn covid tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí covid-19. Apapọ awọn ti oti ni aarun naa lọwọlọwọ bayi jẹ ọgọrun kan ati ọgọta le-marun ẹgbẹrun, ati ookandin-nigba , ọgọrun kan ati aadọta le-marun ẹgbẹrun,ati ẹẹta din ladọrin ati ọkan si ti ni alaafia ti ẹgbẹrun meji ati ọgọta le-mẹta ti jẹpe ọlọrun. Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 312

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button