Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ọmọ orílẹ̀- èdè Nàìjíríà ti ó tó igba ẹgbẹ̀rún lóti lẹ́tọ̀ọ́ láti jànfààní ètò ìranni lọ́wọ́ nípa fífúni lówó-Alákóso ilé -iṣẹ́ ààrẹ

106

Alakoso naa sọ pe igba ẹgbẹrun awọn ọmọ orilẹ -ede Naijiria yoo ni anfaaani si ilana eto ifidimulẹ ọrọ aje(ESP)s nipa fifunni lowo fun atilẹyin awọn okowo kekere ati alabọọde(MSMEs).

Alaye kan lati ile-iṣẹ Alakoso aarẹ ati Igbakeji rẹ sọ pe,apapọ awọn to ti jẹ anfaani eto atilẹyin owo naa lapapọ jakejado orilẹ-ede Naijiria jẹ irinwo le lọgota ati marun ati ogun le-lẹgbẹrin.
Ipolongo sissan owo naa bẹrẹ ni ọjọ kẹẹdọgbọn oṣu kẹrin ninu odun yii.
Eyitayọ Fauziat Oyetunji

Leave A Reply

Your email address will not be published.