Take a fresh look at your lifestyle.

Ọkọ̀ ojú omi alámòjútó tuntun fi orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sílẹ̀ lọ sí ibùdó Pọ́túgàlì

34

Ọkọ oju omi alamojuto tuntun,NNS LANA ti de si Lisbon,iyen orilẹ-ede potugal . eleyii jẹ ipele akọkọ irin-ajo rẹ si orile-ede Naijiria.
Agbẹnusọ fun orilẹ-ede Naijiria,ọgagun Suleiman Dahun ti o soju fun ọga agba ikọ omo ogun oju omi sọ pe,Rear Admiral Perry Onwuzulike ti o se olori awon asoju naa ati awon osise ile- asoju Naijiria ni o gba oko oju omi naa.
Dahun se afikun pe ,oko oju omi naa yoo duro ni orile-ede potugali fun ojo meta,ki o to lọ si Las Palmas,Spain .Oko oju omi NNS LANA naa de ọwọ ikọ ọmọ ogun Naijiria lati orilẹ ede Faranse ni ọjọ kẹẹdogun oṣu kinni, ọdun 2021.

 

 

 

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.