Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19:Àwọn ènìyàn tó ní ààrùn covid 19 di márùún-dì́n-lógójí lórìlẹ̀-èdè Nàìjíríà

50

Ile-iṣẹ ti o n ṣe amojuto gbigbogun ti aarun ni orilẹ-ede Naijiria,NCDC,ti sope awọn ti oni aarun marun-din-logoji tuntun miran ti jẹ yọ nì ọjọ aiku .
Pẹlu nọmba tuntun yii,awọn to ti ni aarun covid jẹ ọgọrun kan ati ọgọta mẹrin o din ọgọrun ati mọkandinlogun ti awọn to ti gba iwosan si jẹ ọgọrun kan ati aadọta o din mẹrin ẹgbẹrun ati mejila ti awọn meji-le lọgọta le-ni -ẹgbẹrun meji si ti jẹ ọlọrun nipe.

Eyitayo Oyetunji

Leave A Reply

Your email address will not be published.