Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì ààrẹ ,Yẹmí Òsínbàjò gbóṣùbà káre láí fún ilé-iṣẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ SecureID

Igbákejì ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò, ti gbóríyìn fún  SecureID Limited, tí ójẹ́  olùpìlẹ̀ṣẹ̀ alákọ́kọ́ ìwé pélébé alásọdowó tiwantiwa , fún fífi ìlànà kalẹ̀ fùn àwọn ilé-iṣẹ́ Nàìjíríà míràn láti…

Gàmbàrí bẹnu àtẹ́ lu ìṣẹ̀lẹ̀ ìdìgunjalè tó wáyé ní Víllà

Ilé-iṣẹ́ ààrẹ ti fìdí ẹ̀ múlẹ̀ wípé , àwọn ọlọ́sà gbìyànjú láti jalè ní ibùgbé olórí àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ ààrẹ Bùhaŕí,Ìbràhím Gàmbàrí. Agbẹnusọ fun ile-iṣẹ aarẹ fi   daniloju pe iṣẹlẹ naa waye  ni alẹ…

Aáwọ̀ okòwò: Ààrẹ Bùhárí rán Àwọn Aṣójú Sí orílẹ̀-èdè Ghánà

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mùhámmádù Bùhárí ti  ṣọ  pé kí  aṣojú kán lọ sí orílẹ̀-èdè Ghánà láti yanjú aáwọ̀ ọlọ́jọ́ pípẹ́  tó ti wà  láàrin àwọn oníṣòwò Nàìjíríà àti ìjọba orílẹ̀-èdè Ghánà.…

Àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ṣe ìlérí Láti ripé àwọn ọmọ ilé-ìwé t́i wọ́n jígbé gba…

Àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú ti pinnu láti sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn tó tọ́ nípa gbígba ìtúsílẹ̀ àwọn ọmọ ilé-ìwé tí wọ́n j́igbé ní Yunifásítì Greenfield ní Ìpínlẹ̀ Kaduna. Abẹnugan ile igbimọ aṣofin naa, Ọgbẹni Femi…
button