Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19:Ènìyàn mọ́kàndín-láàdọ́ta míràn tún ti ní ààrùn covid

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

121

Ilé-iṣẹ́ tó nmójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, NCDC ti mudánilójú pé  àwọn  ènìyàn mọ́kàndín-láàdọ́ta míràn tún ti ní ààrùn covid.

Apapọ  awọn to ti ni aarun naa lọwọlọwọ bayii jẹ ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta le ni ọ̀kẹ́ mẹ̀jọ o le ni èjì-le-ni-ojì din ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta, ẹgbàáta-le-ni-ọ̀kẹ́-mèje-abo o le ni èjì din ni okòó lelọ́ọ̀dúnrún ti gba iwosan ti aàrún-din-ni-ojì din ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ọ̀kànlá si ti jẹ ipe oluwa.

FCT-Mẹtadin-lọgbọn,Lagos-mọkanla,Enugu-mẹjọ,Ọyọ-mẹta.

 

 

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.