Take a fresh look at your lifestyle.

Èǹiyàn ọgọ́rùún mílíọ́nù ti wo àwo Burna Boy báyìí

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

117

Awọn eniyan to to ọgọrun miliọnu ti wo awo mẹta ọtọọtọ ti  ọmọ orilẹ-ede Naijiria to jẹ amin ẹyẹ Grammy,Burna Boy ṣe gbẹyin,’African Giant’,’Outside’,and ‘Twice as Tall’.

Ogbe ’Outside’ jade ni oṣu kinni odun 2018, Grammy yan ’African Giant’  to gbe jade ni oṣu keje ọdun 2019, ti ‘Twice as Tall’, to gbegba olubori si jade ni oṣu kẹjọ ọdun 2020.

Burna Boy ni akọkọ akọrin adulawọ ti awọn eniyan to to ọgọrun miliọnu wo awo rẹ mẹta ọtọọtọ.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.