Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ̀ alákóso ìtọ́sọ́nà ààrẹ ti tako àgékúrú ohùn àfetígbọ́ tó nlọ káàkiri

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

111

Ìgbìmọ̀ alákóso Ìtọ́sọ́nà ààrẹ  (PSC) lórii ààrùn covid, sọ pé àgékúrú ohùn àfetígbọ́ tí alákóso  Orílẹ̀-èdè lábẹ́ PTF nígbàkan rí ń pín kiri lórí ayélujára, kìí ṣe tuntun.

Alaye kan lati ile-iṣẹ  akowe  Ijọba orilẹ-ede sọ pe, agekuru naa jẹ itọsọna totipẹ ati pe ko ni nkankan lati ṣe pẹlu awọn ilana titun.

PSC tun ṣalaye laiṣeaniani pe, awọn ilana  ti o  ṣẹṣẹ fi sita  jẹ atunkọ eyi ti  o tẹjade ni Oṣu Kẹrin Ọjọ kẹtadin-lọgbọn, ọdun 2020 ati pe kii ṣe tuntun bi a ti roo, bikoṣe lati mu awọn ipese awọn ofin idaabobo ilera aarun covid,2021, ti o wa tẹlẹ ni agbara,   ki o si tun le maa jẹ irannileti  pe COVID-19 buru jai.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.