Take a fresh look at your lifestyle.

Ojúmọ́ tuntun àrà tuntun:Wọ́n tún jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé ní ìpínlẹ̀ Niger

Àwọn ọlọ́pàá ti fìdíẹ̀ múlẹ̀ pé lótìtọ́ọ́ ni àwọn kan ti fipá kó àwọn ọmọ ilé-kéu ́ọkùnrin kan  kúrò ní ilé-ìkawé wọn ní agbègbè Tegina ní ìjọba ìbílẹ̀ Rafi, ipinlẹ Niger ní ọjọ́ àìkú. Gẹgẹ bii agbẹnusọ…

Igbákejì ààrẹ yóò darí ìpàdé ìgbìmọ̀ àpapọ̀ lóríi ayélujára

Ìpàdé ìgbìmọ̀ àpapọ̀ ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ ọ̀hún ti bẹ̀rẹ̀ ní víllà, tí igbákejì ààrẹ,Yẹmí Òshínbàjò ṣe adarí rẹ̀ ,nígbàtí ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ńkópa níbi àpèjọ ìsúná àwọn adúláwọ̀ kan ní Paris, ní…

NECO sún ọjọ́ ìdánwò àṣewọlé si àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga síwájú

Ìgbìmọ̀ tó ńmójútó ètò ìṣèdánwò àpapọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ti sún ìdánwò gbogbogboò 2021,sí àwọn ilé-ẹ̀kọ́ àpapọ̀ sí ọjọ karùún,ọjọ́ àbámẹ́ta oṣù kẹfà,ọdún 2021. Agbẹnusọ fun igbimọ naa,…

Enugu:Àwọn jàǹdùkú dáná sun olú ilé-iṣẹ́ àjọ t́i ó ńṣàmójútó ètò ìdìbò

Ile iṣẹ ajọ to nmojuto eto idiboti ke gbajari pe awọn janduku kan ti dana sun ọkọ Hilux mẹfa ni olu ile-iṣẹ wọn ni ọjọ aiku. Kọmiṣọna apapọ ati alaga , oluṣakoso ati Igbimọ idanilẹkọ awọn oludibo,agbẹjọro Festus Okoye fi idi ẹ mulẹ ninu…

Orílẹ̀-eldè Nàìjíríà yóò ṣagbáterù ìpàde àpérò láti kojú ìṣúná ọ̀nà àìtọ́

Ìjọba Nàìjíríà ti parí àwọn ètò láti ṣe àpèjọ káríayé ọlọ́jọ́ méjì lórí àtikojú ìsúná ọ̀nà àìtọ́ (IFFs) àti gbíí́gba dúkìá ìlú tíwọn ṣe báṣubàṣu padà. Ajọ to nrisi idẹkun iwa ibajẹ ati iru awọn iwa…
button