Take a fresh look at your lifestyle.

Làsígbòò Palma:Àwọn aládúgbò sá àsálà fún ẹ̀mí wọn

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

109

Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Mozambic ti agbègbè Palma ti wà ní hílàlílo, tí ọgọ́rùún sí  ńsá lọ lójoojúmọ́, bótilẹ̀jẹ́ pé ,ó tí tó  ọ̀sẹ̀ mẹ́fà sẹ́yìn tí àwọn mùsùlùmí   oníjà kan kọlù ìlú náà, gẹ́gẹ́ bíi àwọn tó ye ìkọlù náà bọ́ àti àwọn amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ fún àwọn òṣìṣẹ́.

Ni ọjọ kẹrinle-logun Oṣu Kẹta, awọn ọlọtẹ naa rọlu  ilu etido ọhun,wọn pa ọpọlọpọ awọn eniyan, ti ogunlọgọ awọn oṣiṣẹ afẹfẹẹ gaasi olowo ọpọlọpọọ biliọnu  dọla Amẹrika si salọ [LNG].

 

Lẹhin ija fun ọpọlọpọ ọjọ, ijọba sọ pe awọn ọmọ-ogun rẹ ti le awọn alakatakiti ọhun lọ ati pe rogbodiyan naa ti lọ silẹ.  Ṣugbọn ọpọlọpọ awọn eniyan ṣi n bẹru ti  awọn kan si n sa kuro ni agbegbe naa.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.