Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ kan ti gba àwon ọ̀dọ́ Yorùbá ni ́ìmọ̀ràn láti yàgò fún Ìwà-ìpáǹle

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

103

Ẹgbẹ kan ni Guusu Iwọ oorun Naijiria, Igbimọ oluwadii ti Ile Yoruba (YAF) ti rawọ ẹbẹ si awọn ọdọ Yoruba lati yago fun iwa-ipanle ati lati gbe ni igbe alaafia pẹlu awọn alabagbe ati awọn eniyan miiran ni agbegbe wọn.
Alakoso apapọ fun ẹgbẹ naa,Ọgbẹni Adeshina Animashahun ni orawọ ẹbẹ naa si wọn lakoko ti o nba awọn oladugbo Akurẹ sọrọ,nibi ti o ti pakiyesi awọn eniyan si pataki lati maa gbe nigbe alaafia ati iṣọkan ni orilẹ-ede Naijiria.

Leave A Reply

Your email address will not be published.