Take a fresh look at your lifestyle.

Ààbò Orílẹ̀-èdè: Àwọn ọmọ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin pè fún àfikún owó láti pèsè ààbò…

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin Orílẹ̀-èdè ń bèèrè fún  owó  tó jọjú  díẹ̀ síi, fún Àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà àti àwọn ilé-iṣẹ́ ààbò míràn, láti le kojú ewu  rògbòdìyàn tí ó ń da orílẹ̀-èdè náà láàmú.…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní dandan jẹ́mánì gbọ́dọ̀ dá gbogbo àwọn nkàn ìṣẹ̀ǹbáyé tí…

Ìjọba Nàìjíríà ti bèèrè fún ìdápadà gbogbo àwọn  ojì-din-lẹwá le ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́fà Idẹ  ti ilu Benin tí wọ́n  gbẹ́sẹ̀ lé  ní orílẹ̀-èdè Áfíríkà ní ọdún 19th, tí wọ́n sì sọ ibùgbé rẹ̀ di   ilé-ìṣọ́ Jẹ́mánì.…

Ilé-iṣẹ́ àwọn ọmọ ogun òfurufú kégbàjarì :’ẹ ṣọ́ra fún ayédèrú ìròyìn gbígba àwọn…

Oludari  Ilé-iṣẹ́ àwọn ọmọ ogun òfurufú (NAF), ti ya ara rẹ̀ kúrò nínú ìkéde tí wọ́n ń pín kiri lórí àwọn ẹ̀rọ ayélujára kan nípa bíbẹ̀rẹ̀ sí ní gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sí  ilé ẹ̀kọ́ gíga  ti Nọ́ọ́sì, NAFCON. NAF…

Ilé-iṣẹ́ tí ó ń tẹ owó ní orílẹ́-èdè Nàìjíríà fi gbegedé sórí títẹ owó jáde

Olùdarí Alákóso, ilé-iṣẹ́ ìtẹwó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, NSPMC, Abbas Umar Masanawa sọ pé, ilé-iṣẹ́ ọ̀hún ti ṣàṣeyọrí tó lámì nínú títẹ  owó síta ní orílẹ̀-èdè Naijiria. Ile-iṣẹ naa tun ni agbara  lati tẹ…

COAS – Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mú ìṣòkan lọ́kùúnkúndùn láti gbógun ti ikọ̀…

Ọ̀gá àgbà fúnilé isẹ  àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà (COAS) ,Ọ̀gágun àgbà Faruk Yahaya àti àwọn ọmọ- ikọ̀ rẹ̀ ,ní Mongadishu Cantonment ní ilé ìjọ́sìn kátólíkì ní Àbújá,  ṣàfihàn àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà gẹ́gẹ́…

COVID-19 : Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tún ti rí ènìyàn mẹ́rìndín-lọ́gọ́ta míràn

Ilé-iṣé tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NCDC) sọ pé àwọn ènìyàn mẹ́rìndín-lógún míràn tún ti kún àwọn ẹ̀rin-le-ni-ojì din ni ẹgbẹ́je tó ti ní ààrùn náà tẹ́lẹ̀ lọ́jọ́ àìkú.…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gáḿbíà fìmọ̀ ṣọ̀kan láti kojú àwọn ọlọ̀tẹ̀.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gáḿbíà ti buwọ́ lu ìwé àdéhùn lórí ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ọmọ ogun láti kojúu àwọn ọ̀daràn tó ń da orílẹ̀ èdè wọn láàmú. Oludamọran pataki si Minisita fun Aabo, Mohammed Abdulkadri,…

Ètò Oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu yóò gbọn òṣì dànù-igbákejì Òsíǹbàjò

Igbákejì ààrẹ, orilẹ ede Naijria, Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀síńbàjò sọ pé,ìgbìyànjú orílè-èdè láti pèsè oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ilànà láti dẹ́rù bòṣì jákèjádò  orilẹ ede Nàìjíríà. Ọjọgbọn…
button