Àwọn arìnrìn àjò Nàìjíríà Parí iṣẹ́ Hajj 2022
Àwọn ọmọ Nàìjíríà tó rìnrìn àjò lọ sí Saudi Arabia lọ́dún yìí pẹ̀lú àwọn tí ó wá láti Ìpínlẹ̀ Kwara ti parí iṣẹ́ Hajj, nígbà tí wọ́n ṣe èyí tí ó kẹ́yìn tíí ṣe àbẹ̀wò sì JAMURAT.
Amirul Hajj nipinle…