Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-iṣẹ́ Súgà Dangote yóò bẹ̀rẹ̀ ìṣelọ́pọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Násáráwá

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 259

Gómìnà ìpínlẹ̀ Násáráwá, ariwá ààrin ìlú Nàìjíríà, Gómìnà Abdullahi Sule, ti sọ pé ilé-iṣẹ́ Súg̀a Dangote yóò bẹ̀rẹ̀ ìṣelọ́pọ̀ láìpẹ́ ní ìpínlẹ̀ náà.

Gomina Sule soro yii lasiko ti o n gbalejo awọn ọmọ egbe oniroyin  ipinlẹ, NUJ, ni Lafia,olu-ilu.

O ṣalaye pe, ẹgbẹ Dangote fun idasile ile-iṣẹ suga ti wa  ni Abuja, ti  yoo si de ipinlẹ wọn laipẹ.

Ó dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ náà fún bí wọ́n ti n ṣiṣẹ wọn bii iṣẹ, nipa fifi  akitiyan ìjọba ní ìpínlẹ̀ náà han si awọn ara ilu,ti ó sì sọ pe bi wọn ṣe n ṣe naa ni ki wọn maa ṣe lọ.ki wọn maa dawọ ẹ duro.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button