Take a fresh look at your lifestyle.

Ònímọ̀ Sáyẹ́nsì Tó Jẹ Ọ̀gá Àgbà Fún Àjọ WHO Rọ Àgbáyé Láti Tako Ìpèníjà Tó Ń bọ̀ Lọ́jọ́ Iwájú.

Ọ̀gá àgbà fún àjọ WHO, Jeremy Great ti rọ àgbáyé àti àwọn adarí láti ṣiṣẹ́ lórí ètò ìlera àti ọ̀rọ̀ òṣèlú ki o lè Dẹkun ìjàmbá to n bó wà lọ́jọ́ iwájú. O ní ọpọlọpọ ẹ̀kọ́ ni àti rí kọ nínú àwọn ìjàmbá to ti ṣẹlẹ̀ sẹ́yìn, èyí yóò jẹ ká…

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Pàṣẹ Gbélé ẹ Lásìko Ìbúra Fún Ààrẹ Tuntun, Ọdún 2023.

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí pàṣẹ fún àwọn ènìyàn láti dí lílọ bíbọ̀ kù ni agbègbè Eagle Square nibi tí ètò ifinisipo Ààrẹ Tuntun yoo ti waye láti aago méjì ọ̀sán ọjọ́ ẹtì. Nínú ọ̀rọ̀ tí ìjọba àpapọ̀ fi ransẹ sí ìta láti ọwọ́ Akọ̀wé fún…

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Fífún Àwọn Ọmọ Ilé Ìwé Ni Oúnjẹ Ní Ìpínlẹ̀ Bayelsa.

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Fífún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ounjẹ ni ìpínlẹ̀ Bayelsa, ki o lẹ jẹ ànfààní láti fí àwọn ọmọ sí ilé ẹ̀kọ́. Ètò yìí ni mínísítà fún ọ̀rọ̀ àwọn ará ìlú àti ọ̀rọ̀ tó ńlọ lórí afẹfẹ , Sadiya Umar Farouq fí…

Mínísítà Fún Ìrìn-àjò Ṣe Ìdágbére Fún Àwọn Mínísítà Tọ́kù.

Ilé iṣé ìjọba tó n mójú tó ọ̀rọ̀ ìrìn-àjò ní wọn tí ṣe ayẹyẹ Ìdágbére Fún Mínísítà fún Ìrìn-àjò ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ọ̀gbẹni Muazu Sambo àti mínísítà fún ìpínlẹ̀ ọmọba Ademola ni ìlú Abuja. Mínísítà Sambo rọ ilé iṣé ìjọba fún Ìrìn-àjò…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Pín Àwọn Èlò Ohun Ìkàwé Fún Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara ti pín àwọn ohun èlò ìkàwé tó tó mílíọ̀nù kàn ole ni ẹgbẹ̀rún kán  fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti rí wí pé ìwé kíkà di ìrọ̀rùn. Alága fún àjọ ẹ̀kọ́ fún ìpínlẹ̀ Kwara, ọ̀mọ̀wé Raheem Adaramaja sọ èyí ni ìlú Ilorin, Olu ìlú…

Àwọn Ọmọ Ológun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Tako Ẹ̀sùn Tí Wọ́n Fi Kàn Wọ́n Nípa Ìwà Ibàjẹ́. 

Àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni àwọn ṣe àkíyèsí àwọn ìròyìn tí ilé ìròyìn Sahara gbé síta lórí wí pé àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ológun n ba ìlú jẹ ,ni èyí tí kò rí bẹ́ẹ̀. Gẹgẹ bí ìròyìn tí sọ ẹgbẹ̀ NA se àkíyèsí wí pé àwọn ìròyìn náà ní…