Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Àwọn Akékòó Gbóríyìn Fún Ààrẹ Tinubu Fún Atilẹyin Rẹ Lórí Ètò Ẹ̀kọ́. 

Ẹgbẹ́ àwọn akékòó ni Orílè-èdè Nàìjíríà (NANS) tí gbóríyìn fún Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu fún èròngbà rere nípa ìdàgbàsókè Ẹ̀kọ́. Ààrẹ fún ẹgbẹ́ NANS Lucky Emonife lo ṣe Igboriyin náà fún Ààrẹ ni ọjọ́rú ní ìlú Abuja Emonife sọ wí pé ìwà…

Ààrẹ  Tinubu Yóò Lọ Síbi Ayẹyẹ Ìfinijóyè Ààrẹ Tuntun Fún Orílẹ̀-èdè Senegal.

Ààrẹ Fún ẹgbẹ́ ECOWAS, ti pàṣẹ fun Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àwọn Gómìnà láti rí wí pé wọn kúrò ni ìlú Abuja ni ọjọ́ ìṣẹgun lọ sí Dakara ni Orílè-èdè sénégal láti lọ ṣe ayẹyẹ Ìfinijóyè Ààrẹ Tuntun fún Orílè-èdè náà Èyí di mímọ ní ọjọ́…

Ṣẹ̀nítọ̀ Paul Chukwuma Fún Ilé Ìwé Rẹ Ni Ọgọrùn Mílíọ̀nù Náírà.

Ọ̀mọ̀wé Paul Chukwuma tí ṣe ìrànlọ́wọ́ ọgọrùn Mílíọ̀nù Mẹwàá Náírà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwé rẹ láti kọ àwọn ilé ikẹkọ ìgbàlódé fún àwọn ọmọ ilé ìwé. Chukwuma tó jẹ lára àwọn akékòó ilé ìwé náà ni ọdún 1989 , ṣe ìrànlọ́wọ́ owó náà láti…

Àwọn Àgbẹ̀ Olóhun Ọ̀sìn Pè Fún Ìtèsíwájú Nípa Fífún Àwọn Ọmọ Ilé Ìwé Ní Oúnjẹ.

Àwọn àgbẹ̀ ọlọhun ọ̀sìn ni ìpínlẹ̀ Ẹkọ tí pé fún ìtèsíwájú fífún àwọn ọmọ ilé ìwé ni oúnjẹ láti mú ìdàgbàsókè àti ìlọsíwájú bá ètò ẹkọ àti àwọn àgbẹ̀ Nínú ibanisọrọ pẹlú àwọn àgbẹ̀ ọlọhun ọ̀sìn ni ọrọ náà ti jáde. Ètò fifun àwọn ọmọ…
button