Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ Dá Gbogbo Síìmù Tí Wọn Kò So Pọ̀ Pẹ̀lú Nọ́ḿbà Ìdánimọ̀ Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà (NIN) Dúró

0 252

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti pàṣẹ  ìdádúró gbogbo àwọn siimu ti wọn ko ni  nọ́mbà ìdánimọ̀ orílẹ̀-èdè (NIN).

Asẹ yi jade lẹyin ti gbendeke ti ijọba fi silẹ fun iforukọsile fun nọmba idanimọ Orilẹ-ede Naijiria  (NIN) pari ni ọjọ kọkanllelọgbọn Oṣu Kẹta 2022.

Asẹ yi jade ninu atẹjade kan ti Igbimọ  awọn Minisita  Lori  eto isopọ SIM / NIN gbe jade ni ọjọ kẹrin, Oṣu Kẹta 2022 ti Oludari, Awujọ, Igbimọ Ibaraẹnisọrọ Naijiria (NCC), Dokita Ikechukwu Adinde ati Alakoso, Igbimọ Ibaraẹnisọrọ, National Identity Management Commission (NIMC), Kayode Adegoke fi ọwọ si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button