Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ Jẹ́ Kí Ìbágbépọ̀ Àlááfìà Pẹ̀lú Gbogbo Ènìyàn Ní Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà Gbé Igbá Orókè lọ́kàn Yín

0 259

Bí àwọn Mùsùlùmí káákìri àgbáyé ṣe  bẹ̀rẹ̀ ààwẹ̀ oṣù Ramadan, Sultan ti Sokoto ati Alakoso Gbogbo Igbimọ  Islam, Alhaji Sa’ad Abubakar ti kesi awọn Musulumi Naijiria lati jẹ ki ibagbepọ alaafia pẹlu gbogbo eniyan ni orilẹ-ede naa gbe igba oroke lọkan wọn.

Sultan ṣe ipe yii ni Ipinle Sokoto, nigba ti o kede ibẹrẹ aawẹ 2022 ninu oṣu mimọ ti Ramadan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button