Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà tẹ́lẹ̀rí, Obasanjo ti dìbò

0 297

Aarẹ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà tẹ́lẹ̀rí, Obasanjo ti dìbò, ósì tún gbóṣùbà fún àwọn àjọ elétò ìbò

Obasanjo ti o dibo ni agbègbè ìdìbò kejilelogun, wọọdu kọkanla, ilé Olushomi, ní Abeokuta North ni dédé  aago mẹwa ààbọ̀ àárọ̀ gbóríyìn fún àwọn elétò ìbò fún iṣẹ́ takuntakun ti wọn ṣe ni pa síse alfihàn imọ ẹrọ tuntun BVAS, o sọ wipe o tẹ oun lorun gidigidi, kódà, igba ti wọn ni ki oun yọ ìgò oju rẹ̀ ti wọn si gbe ẹrọ ayaworan si oun loju, iyalẹnu lo jẹ fún oun nígbà tí àworan re yọ níbẹ̀

 

Ọláyinká Akíntọ́lá

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button