Take a fresh look at your lifestyle.

”Ipò bàbá mú mi fòpin sí àwọn ìwà pálapàla” –Zlatan Ibile

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 221

Akọrin Nàìjíríà, Omoniyi Temidayo Raphael, tí gbogbo ayé mọ̀ sí Zlatan Ibile, ti ṣíṣọ lójú àwọn àṣeyọrí rẹ̀  méjì tó ga jù láyé.
Zlatan sọ pé ipa òun bíi bàbá àti orin òun ti yí àwọn nǹkan tó pọ̀ padà lára òun.
Ó sọ síwájú pé òun wá mọ̀ báyìí pé,òun kò rí àmúyangàn nínú àwọn ìwà pálapàla tí òun ti hù sẹ́yìn,pàápàá jùlọ nígbà tí òun ń polongo orin òun.


Nígbà tí ó  ka àwọn ìyípadà náà,ó sọ pé nígbà tí òun wo fídíò àwọn orin tí òun ti ṣe kọjá,tí òun ti ń jó pẹ̀lú  aṣọ tó fara sílẹ̀ lójú òpópónà,ó wá ròó pé yóò fẹ́ẹ̀ le fún òun láti bá ọmọ òun wí tí ó bá ń tọ irú ọ̀nà bẹ́ẹ̀.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button