Take a fresh look at your lifestyle.

Olùdíje fún ipò Ààrẹ lábẹ́ àsìà ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party, LP ti dìbò

0 255

Olùdíje fún ipò Ààrẹ lábẹ́ àsìà ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party, LP, Ọgbeni Peter Obi àti Iyawo rẹẹ̀ Margaret Brownson Obi  ti dibo ni wọ́ọ̀dù Amatutu keji, ẹ̀ka 019, ní àdúgbò Agulu ni ìjọba ìbílẹ̀ Anaocha.

Obi, ti o dibo ni nkan bi aago mejila ku iseju meedogun owurọ, sọ pe òun mọ̀ dájú wípé òun yóò gbé igbá orókè

Ó sọ fún àwọn oníròyìn pé bi ibo ṣe n lọ tẹ oun lọrun gidigidi, o si gbà wọ́n níyànjú pe ki o ma lọ bẹ ni àwọn agbgbe yòókù.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button