Take a fresh look at your lifestyle.

Ètò Ìdìbò Tí bẹ̀rẹ̀ Ní Pẹrẹwú Ní Ìpínlẹ̀ Nasarawa.

0 323

Ètò ìdìbò tí bẹ̀rẹ̀ ní ibùdó ètò ìdìbò, ẹ̀ka 002, Gudi, agbègbè Akwanga, ní ìpínlẹ̀ Nasarawa, Àárín gbùngbùn Àríwá.

Àwọn olúdìbò ń ṣàyẹ̀wò orúkọ wọ́n láti inú ìwé orúkọ àjọ élétó ìdìbò INEC, làkókò tí àwọn òun èlò ìdìbò tí ń dé..

 

Lekan Orenuga

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button