Take a fresh look at your lifestyle.

Adájọ́ Àgbà Ìpínlẹ̀ Ebonyi ti Dìbò.

0 229

Adájọ́ àgbà pátápátá àti kọmísọ́nà fún ìdájọ ni ìpínlẹ̀ Ebonyi, agbófinró Cletus Ofoke tí gbóríyìn fún àjọ elẹ́tò ìdìbò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún mímú ẹ̀rọ tuntun ti yóò mú ìdìbò náà rọrùn wá síta

 

Ìkíni yìí waye ní kété ti Ofoke tẹ̀ka ìbò rẹ ni ilè ẹkọ alakọbẹrẹ Agbaja tí o wà ní ìjọba ìbílẹ̀ izzi.

O ní èrò yìí mú kí iṣé náà yà kíákíá láì sí ìdádúró kankan ni àwọn ẹka ètò ìdìbò náà.

 

Adájọ́ àgbà pátápátá náà rọ gbogbo àwọn ènìyàn láti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ sùúrù ti wọ́n tí ní láti ẹ̀yìn wá.

Adegbite oyebisi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button