Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Tẹ́lẹ̀ Rí, Goodluck Jonathan pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ Dame Patience Jonathan ti di Ìbò wọn.
Wọ́n dìí ní dédé aago mọ́kànlá ààbọ̀ kọjá ìṣẹ́jú kan ní wọ́ọ̀dù kẹtàlá, ìpín kọkàndínlógún, ìlú Otuoke, ní Ìpínlẹ̀ Bayelsa.
Bíótilẹ̀ jẹ́ wí pé, àjọ elétò ìdìbò pẹ́ díẹ̀ kí wọ́n tó dé, gbogbo ètò náà lọ ní àlàáfíà.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply