Take a fresh look at your lifestyle.

NMA rọ ìjọba Láti Ṣe àtúnṣe Ètò Ìlera Nàìjíríà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 332

Ẹgbẹ́  Ìṣòògùn Nàìjíríà (NMA), ti rọ àwọn òṣèlú tó ń ṣèjọba ní orílẹ̀-èdè láti fòpin sí ṣíṣe ìrìn-àjò fún ìtọ́jú ara kí wọ́n sì ṣàtúnṣe ètò ìlera torílẹ́-èdè.

NMA tun gbadura fun Igbakeji Aarẹ, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo fun alekun ilera ni kiakia ati ni kikun latarii iṣẹ  abẹ ẹsẹ ti wọn ṣe fun ti o waye ni ọjọ Abamẹta ni ile-iwosan Duchess International,ni GRA, Ikẹja,nilu Eko.

Gẹgẹ bi atẹjade ti Aarẹ NMA, Dokita Uche Ojinmah gbe jade, ẹgbẹ naa yìn Igbakeji Aarẹ fun fifi igbẹkẹle rẹ han si dokita Naijiria ati eto ilera ti orilẹ-ede.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button