Àjọ tó ń bójútó ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ lorilẹ ede Naijiria (NCC) ti fi dá àwọn ọmọ Nàíjírià lójú pé ẹrọ alatagba netwọọki 5G kò béwudé rárá.
Igbakeji alaga fun igbimọ naa, Ọjọgbọn Umar Danbatta lo sọ eyi ni ọjọ Aje. O tun se alaye pe, agbekalẹ ti wa lati koju awọn ikọlu ti o le de ba ìlo ẹrọ ibaraẹnisọrọ.
Ọjọgbọn Umar so wi pe netwọọki 5G dara fun idagbasoke eto ọrọ ajé orilẹ ede Niajiria.

Leave a Reply