Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Ìpińlẹ̀ Èkó Ti Ààtaǹ Ìdalẹ̀nù Fún Ọjọ́ Méjì gbáko

0 215

Àjọ tó ń bójútó ètò ìdalẹ̀nù ní ìpińlẹ̀ Èkó ti pinnu láti ti ààtaǹto wa ni  Olusosun ní agbègbè Ọjọ́ta fun ọjọ́ méjì gbako, lati ọjọ́ kẹwà, oṣuń kokoǹlá, ọdun yii.

Ajọ naa gbé igbesẹ yii lati le se itọju ti o peye ni agbegbe aatan naa fun ọjọ meji ti wọn yoo fi ti aatan naa pa, amọsa ajọ naa ti pese ọna miran lati lee maa da panti si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button