Kò Séwu Lóko Alóńgẹ ẹ̀rọ alátagbà Netwọọki 5G
Àjọ tó ń bójútó ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ lorilẹ ede Naijiria (NCC) ti fi dá àwọn ọmọ Nàíjírià lójú pé ẹrọ alatagba netwọọki 5G kò béwudé rárá.
Igbakeji alaga fun igbimọ naa, Ọjọgbọn Umar Danbatta lo sọ eyi ni ọjọ Aje.…