Take a fresh look at your lifestyle.

Kò Séwu Lóko Alóńgẹ ẹ̀rọ alátagbà Netwọọki 5G

50

Àjọ tó ń bójútó ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ lorilẹ ede Naijiria (NCC) ti fi dá àwọn ọmọ Nàíjírià lójú pé  ẹrọ alatagba netwọọki 5G  kò béwudé rárá.

Igbakeji alaga fun igbimọ naa, Ọjọgbọn Umar Danbatta lo sọ eyi ni ọjọ Aje. O tun se alaye pe, agbekalẹ ti wa lati koju awọn ikọlu ti o le de ba ìlo ẹrọ ibaraẹnisọrọ.

Ọjọgbọn Umar so wi pe netwọọki 5G dara fun idagbasoke eto ọrọ ajé orilẹ ede  Niajiria.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.