ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ
- Ètò Ìdóòla Ẹ̀mí Parí Níbi Ilé Tó Dáwó Lulẹ̀ Ní South Africa
- Ìdíje NWFL Super Six: Ikọ̀ Confluence Àti Ikọ̀ Edo Yóò Kojú Ara Wọn
- Òjò Líle, Àgbàrá Òjò Gbẹ̀mí Àádọ̀ta Èniyàn Ní Afghanistan
- Brazil Yóò Gbàlejò Ìdíje Ifẹ Ẹ̀yẹ Àgbáyé Bọ́ọ̀lù Àwọn Obìnrín FIFA Ọdún 2027
- South Africa fòpin sí akitiyan ìrànlọ́wọ́ níbi ilé tí ó dàwó
- Senegal:Igbákejì alákòóso tako ológun Faransé
- Gaza: Ológun Israeli rí oku àwọn mẹ́ta tí wọ́n mú sílẹ̀
- Ìjọba Gúúsù Sudan àti Ẹgbẹ́ Ọlọ́tẹ̀ buwọ́lu ìpinnu àlàáfíà
- Àyájọ́ Ẹ̀jẹ̀ ríru Àgbáyé: Ìjọba Anambra ṣe àgbékalẹ̀ àyẹ̀wò ọ̀fẹ́
- Mínísítà fún ètò ìbáraẹnisọrọ̀ pinnu láti ṣàtìlẹyìn fún EFCC bí ó ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ẹ̀rọ Asọ̀rọ̀ máá gbèsì
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
Gaza: Ológun Israeli rí oku àwọn mẹ́ta tí wọ́n mú sílẹ̀
Ológun Israeli ti rí òkú àwọn mẹ́ta tí wọ́n mú sílẹ̀ ní Gaza Strip,ní Ọjọ́ọ́rú, ọ̀gá àgbà agbẹnusọ…
Àkọ̀tun Ìkọlù Wáyé Sí Gaza, Ọ̀pọ̀ Ẹ̀mí Àti Dúkìá Sòfò
Ìkọlù láti ọwọ́ Orílẹ̀-èdè Isreal sí Gaza tẹ̀síwájú, níbi ti ènìyàn méje ti pàdánù ẹ̀mí ní…
Netanyahu Gbáradì Láti Kojú Ìdẹ́yẹsí Tí Ó Se é Se Kí Ó Wáyé Láti Ọwọ́…
Benjamin Netanyahu ti Orílẹ̀-èdè Isreal ti gbáradì láti dojúkọ èyíkéyìí ìdẹ́yẹsí tí ó se é se kí…
Omíyalé Sọ Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ènìyàn Di Aláì-nílé Ní Orílẹ̀-èdè China
Ènìyàn tí kò dín ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́ta ni ẹ̀kún omi ti lé kúrò ní ibùgbé wọn ní Guangdong…
ÌRÒYÌN ÀṢÀ ÀTI ÌṢE YORÙBÁ
Nàìjíríà Yóò Kópa Níbi Ìpàtẹọjà Àṣà Ni Orílẹ̀-èdè Italy
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò kópa nibi Ìpàdé ọja Àṣà agbaye ni ilu Venice Biennale ti yóò bẹrẹ ni ọjọ…
ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ
Mínísítà fún ètò ìbáraẹnisọrọ̀ pinnu láti ṣàtìlẹyìn fún EFCC bí ó…
Mínísítà fún ètò ìbáraẹnisọrọ̀ àti Ìṣàlàyé, Mohammed Idris ti sọ pé ó ṣe pàtàkì fún Ìgbìmọ̀…
ÌRÒYÌN ÁFÍRÍKÀ
Ètò Ìdóòla Ẹ̀mí Parí Níbi Ilé Tó Dáwó Lulẹ̀ Ní South Africa
Ètò Idoola ẹ̀mí ti pari níbi ilé tó dàwó lulẹ̀ ni George, South Africa .
Lẹ́yìn igbiyanju ọjọ mejila,…
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Yàn Tuntun, Se Àtúnyàn Àwọn Àgbà Àgbà Òṣìṣẹ́ Ilé Iṣẹ́ Ìjọba
Gómìnà ipinle Kwara,aarin gbùngbùn Ariwa orile-ede Naijiria AbdulRahman AbdulRazaq ti ṣe atuyan omobabinrin Bukola Babalola gẹgẹ bí igbakeji olori awọn oṣiṣẹ-Deputy Chief of Staff (DCOS).
Bi akọsilẹ lati ọdọ oga agba akowe…
Ilé Aṣòfin Ipinlẹ Kogi Rọ Gómìnà Ododo Láti Túbọ̀ Múlele Lórí Ètò Ààbò Ní Àwọn Ilé Ẹ̀kọ́ Gíga Àgbà
Ilé aṣòfin ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ ipinlẹ kogi ti rọ gomina Usman Ododo lati fi kun awọn eleto ààbò lati dẹkun ìwà ajinigbe ni ile ẹkọ gíga àgbà patapata ni ipinlẹ náà.
Ọmọ ẹgbẹ igbimọ to soju ipin ẹka Adavi Kọ̀ǹsítúẹ́sì, Asema Haruna bú…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Dárúkọ Òṣìṣẹ́ Ìdàgbàsókè Ìjọba Ìbílẹ̀ Mẹ́rìndínlógún Tuntun
Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinle Kwara, aarin gbùngbùn Naijiria ti buwọ́lù iyansipo awọn òṣiṣẹ Idagbasoke Ìjọba Ìbílè Mẹ́rìndínlógún
-16 local government area development officers (LGA-DOs).
Governor…
APC Zamfara bẹnu àtẹ́ lu atótónu ìdádúró Alága ìpínlẹ̀
Ikọ̀ ìpínlẹ̀ Zamfara ti ẹgbẹ́ẹ òṣèlú All Progressives Congress (APC), ti kọ atótónu ìdádúró Alága ìpínlẹ̀, Tukur Danfulani.
Eleyi jẹyọ ninu alaye kan ti akọwe ipolongo APC ti ipinlẹ,Malam Yusuf Idris fi sita ni Gusau, ni…
ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ
Ọdún NIHOTOUR Gastronomy Se Àpèjúwe Irinajo Àbẹwò Àti Ìtọjú Ṣiṣe – Ọ̀gá Àgbà…
Ọ̀gá Àgbà àjọ National Institute for Hospitality and Tourism (NIHOTOUR), Alhaji Nura Kangiwa, ti sọ pe…
ÌRÒYÌN ÌLERA
Àyájọ́ Ẹ̀jẹ̀ ríru Àgbáyé: Ìjọba Anambra ṣe àgbékalẹ̀ àyẹ̀wò ọ̀fẹ́
Ìjọba Anambra nípasẹ̀ Ilé Iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tí ń mójútó ètò ìlera, ti ṣe àgbékalẹ̀ àyẹ̀wò ọ̀fẹ́…
Àjọ USAID Fẹ́ Kọ́ Àwọn Àádọ̀rin Ọ̀dọ́bìnrin Ìpínlẹ̀ Bauchi Ní Ẹ̀kọ́ Nípa Ètò Ìmọ̀…
Àjọ United States International Development Agency Health WorkForce Management (USAID-HWM) project sọ pe…