Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ̀ Aláse Ti Nàìjíríà Fi Ọwọ́ Sí Owó Tó Lé Ní Bílíónù Mẹ́rìnlá (N14.3) Fún Ètò N-Power

0 256

Ìgbìmọ̀ Aláse ti Nàìjíríà ti fi ọwọ́ si owó tó lé ní bilionu mẹ́rìnlá (N14.3) fún ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àti ìdánilókòwò àwọn tó jẹ àǹfàńi ètò N-Power, ọ̀kan nínú àwọn ètò  tí ìjọba gbé kalẹ̀ fún ìlọsíwájú àwùjọ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Minisita fun ọrọ ọmọniyan, isakoso ajalu ati idagbasoke awujọ, Sadiya Farouq sọ eyi lakoko ti o n ba awọn oniroyin ṣorọ lẹyin ipade Ọjọrú ti Igbimọ Alase ijọba apapọ leyi ti Aarẹ Muhammadu Buhari ṣakoso.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button