Take a fresh look at your lifestyle.

A Ó Parí Afárá Niger Kejì Kí Ọdún Yí Tó Dópin

0 262

Ìjọba Nàìjíríà sọ pé ọ̀kan nínú àwọn ohun èlò ìgbàlódé pàtàkì tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni afárá Niger kejì tí ó so apá ìlà-òòrùn pọ̀ mọ́ àwọn ìpínlẹ̀ míràn; isẹ́ ti ń lọ lórí rẹ, ó sì ku díẹ̀ kí ó parí.

Minisita fun iṣẹ ati Eto igbele, Babatunde Fashola, ṣe alaye eyi ni ọjọ  Ojobo lakoko apejọ ọsẹsẹ ti awọn minisita ni ile-igbimọ, Ilu Abuja.

O sọ pe afara naa, eyi ti o yẹ ki o ti pari ni oṣu keji ọdun 2022, ni o ti wa ni idaduro nitori ifẹhọnuhan EndSARS ti o sẹlẹ laipẹ ọjọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button