Take a fresh look at your lifestyle.

Emir Kano Sí Gbọ̀ngàn Ilé Ìwòsàn Ńlá Ní Cross River

0 241

Emir ti ilu Kano, Alhaji Ado Bayero sí ilé ìwòsàn ní ọjọ́ Àbámẹ́ta ní Ìpinlẹ̀ Cross River. Ilé ìwòsàn naa jẹ ara àkànse iṣẹ́ tí Gomina Ben Ayade se, léyìí tí o le e gba ogóje aláàrẹ́ẹ̀ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo.

 

Alayeluwa salaye pe o je ohun iwuri fun oun lati lọ si irufẹ àkanse iṣẹ́ beẹ ni Cross River.

 

Ile iwosan naa jẹ dida silẹ pẹlu ifọwọsowọpọ ajọ Coscharis, lati jẹ ki o jẹ ile iwosan akọkọ ti yoo dara julọ fun itọju ọmọniyan.

O salaye siwaju pe, apejuwe ile iwosan Obudu- German naa da bi ile iwosan Orilẹ-ede Germany.

 

Wọ́n gbóríyìn fún Gomina Ayade gẹgẹ bi adari rere, ti o bẹrẹ ile iwosan naa ni ọdun 2020, o si pari rẹ ni ọdun 2023.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button