Browsing Category
ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ
This is a Nigeria news category
Mínísítà Fún Iṣẹ́ Nàìjíríà Bú-Ẹnu-Àtẹ-Lú Ìwà Ìbàjẹ́ Ni Òpópónà Èkó Sí Calabar
Mínísítà fún Iṣẹ́ ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Dave Umahi, tí bú-ẹnu-àtẹ-lú àwọn ìwà ìbàjẹ́ àwọn ènìyàn ní òpópónà Èkó sí Calabar, Ó sí kìlọ̀ pé ọwọ́ òfin yóò mú àwọn tó ń hu ìwà ìbàjẹ́ náà.
Mínísítà ṣe ìkìlọ náà nígbà àyẹwò iṣẹ rẹ̀ ní…
Ìpínlẹ̀ Oyo fọwọ́ sí Àdéhùn Pẹ̀lú ilé Iṣẹ́ iṣẹ́ Agbára
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Oyo, nípasẹ̀ Ilé Iṣẹ́ Àyíká àti Àwọn Ohun Àdánidá, ti fọwọ́ sí àdéhùn pàtàkì kan pẹ̀lú ilé iṣẹ́ agbára kan, tí a fẹ́ mú kí àwọn ètò àti ìlànà ojúọjọ́ rẹ̀ lágbára sí i, tí ó dojúkọ ìṣàkóso àyíká
Kọmíṣọ́nà fún Àyíká àti Àwọn…
Ààrẹ Tinubu Rọ̀ Àwọn Ènìyàn Láti Dibò Alalafia Ní FCT, Kano, Àti Ipinlẹ Rivers
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti rọ àwọn olùdìbò tó yẹ ní Federal Capital Territory (FCT), Kano àti Rivers láti kópa nínú ìdìbò ní ọjọ́ Àbámẹ́ta láìsí ìbẹ̀rù, ó ń ké sí àwọn òṣèlú láti yẹra fún ìwà ipá àti ìwà ìgbónára.
Nínú ìkéde kan…
Báńkì fún Iṣẹ́ Àgbẹ̀ Gbóríyìn fún Ìgbìyànjú Ìyàwó Àkọ́kọ́ Lórí Oúnjẹ Tí Kò Péye
Olùdarí Àgbà fún Báńkì fún Iṣẹ́ Àgbẹ̀, Ayo Sotinrin ti gbóríyìn fún àwọn ètò iṣẹ́ àgbẹ̀ àti oúnjẹ tí Ìyàwó Àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà, Sẹ́nétọ̀ Oluremi Tinubu, ṣe, ó sì ṣàpèjúwe wọn gẹ́gẹ́ bí àwọn ìgbòkègbodò tó lágbára tó ń mú ààbò oúnjẹ lágbára…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Nasarawa Fẹ́ kọ́ NIPR Yunifásitì
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Nasarawa ti sọ pé àwọn ètò ń lọ lọ́wọ́ láti kọ́ Ilé-ẹ̀kọ́ Ìbáṣepọ̀ Gbogbogbòò ti Nàìjíríà " NIPR University sí ìpínlẹ̀ náà.
Gómìnà Abdullahi Sule ṣe ìfihàn náà nígbà tí ó gba àwọn aṣojú láti ilé ise Voice of…
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Àti Orílẹ̀-èdè Jámánì Ṣèlérí Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Nínú Agbára, Ààbò, Àti Ọ̀nà ojú…
Ààrẹ Bola Tinubu àti Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Jámánì Friedrich Merz ti pinnu láti mú kí àjọṣepọ̀ àárín gbùngbùn lágbára sí i àti láti mú kí àjọṣepọ̀ pọ̀ sí i nínú ààbò, agbára, àti àwọn ẹ̀ka ọkọ̀ ojú irin.
Nínú ìjíròrò lórí tẹlifóònù, àwọn olórí…
Àjọ NIMC Yóò Bẹ̀rẹ̀ Ìforúkọsílẹ̀ Ní gbogbo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Pátá.
Ìgbìmọ̀ Ìṣàkóso Ìdánimọ̀ ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NIMC), sọ wí pé ó ti múra tán láti bẹ̀rẹ̀ ìforúkọsílẹ̀ ní ìpele gbogbo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún ìforúkọsílẹ̀ Nọ́mbà Ìdánimọ̀ (NIN) ní ìbámu pẹ̀lú àṣẹ Ààrẹ tí ó pàṣẹ fún Ìgbìmọ̀ Ìṣàkóso…
Ramadan: Gómìnà ìpínlẹ̀ Gombe Bèrè Adúrà Fun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Gombe, Muhammadu Inuwa Yahaya, ti ke si awon Musulumi ni ìpínlẹ̀ náà ati gbogbo ènìyàn láti ni ádùrá fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lásìkò oṣù Ramadan yìí .
Ninu ifiranṣẹ rere lati ṣe ayẹyẹ ibẹrẹ ààwẹ̀ Ramadan, Gomina Yahaya…
Mínísítà Fún Ilu Abuja Gboriyin Fún Ààrẹ Tinubu Látàrí Òfin Ìdìbò
Mínísítà fun Agbegbe Olu-ilu Apapo Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Abuja Nyesom Wike, ti yin Ààrẹ Bola Tinubu fun fífọwọ́ sí Òfin Ìdìbò ti odun 2026 (Àtúnṣe) ní kíákíá.
Nínú ìròyìn kan tí Olùrànlọ́wọ́ pàtàkì rẹ̀ lórí Ìbánisọ̀rọ̀ gbogbogbòò àti…
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣe Àjọyọ̀ Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Gambia Fún Àyájọ́ Ọjọ̀ Òmìnira
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti fi ìkíni ayọ̀ hàn sí Ìjọba àti àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Gambia bí orílẹ̀-èdè náà ṣe ń ṣe ayẹyẹ Ọjọ́ Òmìnira rẹ̀, tí wọ́n ń ṣe ìrántí ìpele ìjọba-ayé ní ọdún 1965.
Nínú ìránṣẹ́ rere tí agbẹnusọ fún Ilé-iṣẹ́ fún…