Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN

This is a category for featured story

Ìpínlẹ̀ Cross River: Àwọn ọlọ́pàá Ti Sẹ Àkọsílẹ̀ Ìdàgbàsókè Pàtàkì Ṣí Ẹgbẹ́ Ìṣòwò Ọjà.

Àwọn ọlọ́pàá  Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tú ẹgbẹ́ ìṣòwò ọjà kan ká, wọ́n sì ti gba àwọn ènìyàn tó lé ní ọgọ́rùn-ún tí ilé iṣẹ́ ọ̀daràn náà kàn là. Ọ̀rọ̀ tí Alága Ìbánisọ̀rọ̀ Ọlọ́pàá, Olú-iṣẹ́ Zone 6, Calabar,  ni Ìpínlẹ̀ Cross River,…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Gba Owó Ìbẹ̀rẹ̀  Àádọta Mílíọ̀nù Dọ́là$ Nípasẹ̀ Ìbáṣepọ̀ NSIA–JICA

Aláṣẹ Ìdókòwò Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NSIA) àti Ilé Iṣẹ́ Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Àgbáyé ti  Orílẹ̀-èdè Japan (JICA) ti parí àdéhùn láti ṣe ìfilọ́lẹ̀ Owó Ìmúdàgba Àádọta mílíọ̀nù Dọ́là láti mú kí ètò ìṣẹ̀dá tuntun ní  Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lágbára síi.…

Aṣojú Ìṣúra  Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà Ṣè Àbẹ̀wò sí  Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Olùrànlọ́wọ́ Akọ̀wé fún Ìṣúra ni Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, Jonathan Burke yóò ṣè àbẹ̀wò sí  Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ọjọ́ kẹtàlélógún sí ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kejì, láti mú kí àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Ìjọba Nàìjíríà lágbára síi lórí gbígbógun ti owó ìnáwó…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún Àwọn olùfowópamọ́  Kẹ́rẹ́je Ni  Ààbò òfin.

Mínísítà fún Ìdàgbàsókè Àwọn Ohun Alumọ́ọ́nì Rírọrùn ní  Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Dele Alake, ti fi dá àwọn olùfowópamọ́ sí orílẹ̀-èdè òkèèrè ní ẹ̀ka iwakusa orílẹ̀-èdè náà lójú nípa ààbò òfin tó lágbára lábẹ́ àdéhùn Cape Town lórí Àwọn Ohun…

Ẹgbẹ́ APC Ìpínlẹ̀ Kwara Fọwọ́sí Àwọn Olórí Ẹgbẹ́ Tuntun

Àwọn Olórí ẹgbẹ́ òṣèlú 'All Progressives Congress APC' ti Ìpínlẹ̀ Kwara ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, tún gbá àṣẹ láti tẹ̀síwájú ṣe olórí jákèjádò Ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rindínlógún pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ gbogbo ọmọ ẹgbẹ́. ‎ ‎ Ìgbésẹ̀ náà, èyítí o fa àwọn…

Gómìnà Kano Gbóríyìn Fún INEC Àti Àwon Ilé-iṣẹ́ Ààbò Fún Ìdìbò Àlàáfíà

‎Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano, Abba Yusuf, ti yín Ìgbìmọ̀ Elétò Ìdìbò Olómìnira Orílẹ̀-èdè (INEC), àti àwọn ilé-iṣẹ́ ààbò fún iṣẹ́ àlàáfíà àti ìlànà tí ìdìbò abẹ́lé ní Ìpínlẹ̀ náà. ‎ ‎ Ìyìn Gómìnà náà ní a gbé jáde nínú àtẹ̀jáde kán tí agbẹnusọ…
button