Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN

This is a category for featured story

Ìrìn Àjò Afẹ́: Makinde Ṣèlérí Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Oludókòwò

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí pé ìṣèjọba òun ti ṣetán láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn Oludókòwò lójúnà àti mú ọrọ̀ ajé tó wà nínú ìrìn àjò afẹ́ ni Ìpínlẹ̀ náà jáde. Makinde tún ṣèlérí wí pé òun yóò pèsè ìkúnlọ́wọ́ fún gbogbo…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣetán Fún Ìbáṣepọ̀ Tó Jinlẹ̀ Pẹ̀lú Orílẹ-èdè Tanzania.

Akọ̀wé àgbà fún ilé iṣé ìjọba fún ètò Ààbò, ọ̀mọ̀wé Ibrahim Abubakar Kana sọ wí pé Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣetán fún ìtèsíwájú ìbáṣepọ̀ tó dán móran pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Tanzania. Ọ̀mọ̀wé Kana sọ èyí di mímọ nígbà tí ó gbàlejò láti…

Adari ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Anambra Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Gbingbin Ẹ̀gẹ́

Adarí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀gbẹ́ni Somtochukwu Udeze ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ gbingbin ẹ̀gẹ́ ni ìjọba ìbílẹ̀ atani, Ogbaru ni ìpínlẹ̀ Anambra Ó ni ìfilọ́lẹ̀ yìí yóò mú ìdàgbàsókè àti ìlọsíwájú bá ètò ọ̀gbìn fún àwọn agbègbè tó wa…

Òbí Tí A Bá Rí Ní Agbègbè Gbọgán Ìdánwò Yóò Ba Ará Rẹ Láàgọ́ Ọlọ́pàá.: Àjọ JAMB.

Àjọ tó n mójú tó ètò ìdánwò a ti wọlé sí ilé ẹ̀kọ́ gíga JAMB ti ṣe ìkìlọ tí o ni agbára wí pé àwọn òbí ti o ba yọjú sí àgbègbè ibi ìdánwò ki wọn mú gbà àgọ Ọlọ́pàá lo. Ìdánwò náà yóò bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kọkànldinlogun oṣù kẹrin sí ọjọ́…
button