Browsing Category
ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ
This is a category for TRENDING NOW
Nàìjíríà ṣàfilọ́lẹ̀ ìṣàyẹ̀wò ààrùn jẹjerẹ ọ̀fẹ́ jákèjádò orílẹ̀-èdè
Ìjọba Nàìjíríà ti ṣàfilọ́lẹ̀ ètò ìṣàyẹ̀wò ààrùn jẹjerẹ ọ̀fẹ́ jákèjádò orílẹ̀-èdè,tí yọ́ò ṣètọ́jú ẹgbẹ̀rún mẹ́fà ènìyàn jákèjádò ẹkùn mẹ́fà orílẹ̀-èdè. Ètò yìí wà lára àtúnṣe ìgbìyànjú…
Ààrẹ Tinubu ṣèpàdé pẹ̀lú Adarí Ìṣọ̀kan àwọn orílẹ̀-èdè Adúláwọ̀
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu gbàlejò Adarí Ìṣọ̀kan àwọn orílẹ̀-èdè Adúláwọ̀ (AFRICOM), Ajagun Dagvin Anderson, ní ọjọ́ Aiku ní ilé isẹ́ orílẹ-èdè, Abuja.
Àwọn ti o wà nijokoo nibi ipade naa ni Oludamọran lori ọrọ aabo…
Àjọ NMDPRA Ti Ilé Epo Pa Látàri Ìwà Màgòmágó
Àjọ, The Nigeria Midstream and Downstream Petroleum Regulatory Authority (NMDPRA), ti ti ilé epo pa ní ilu
Port Harcourt ipinlẹ Rivers látàri ìwà màgòmágó sì epo Pẹntiróòlù -Premium Motor Spirit (PMS).
Nígbàtí ó ní sọrọ nibi…
Àjọ NSC Faramọ́ Ìgbàlejò Ìdíje Eré Gọ́ọ̀fù
Àjọ National Sports Commission (NSC), ti faramọ́ Igbalejo idije ere Gọ́ọ̀fù ti All Africa Challenge Trophy (AACT), ọdún 2026 fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti yóò wáyé ní
IBB International Golf and Country Club ní ìlú Abuja.
…
Òsìsẹ́ Elétò Ìdìbò Ló Fa Èrò Tó Kéré Láti Dìbò – Alága Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC
Alaga àpapọ ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC), Ọjọgbọn Nentawe Yilwatda ti sọ pé Osise ètò ìdìbò to pọ̀ wà lára okunfa oludibo to kéré jọjọ.
Èyí jẹyọ bakanna lati odò oludamọran pataki sì alaga apapo egbé oselu APC…
Ilé Ìṣẹ́ DHQ Bu Ẹnu Àtẹ́ Lu Ikọ̀lù Ìpínlẹ̀ Kwara
Ilé Iṣẹ Defence Headquarters (DHQ) ti kẹ́dùn, wọn sì ti bu ẹnu àtẹ́ lu ikọlu sì àwọn ènìyàn àti agbègbè Wòrò ní ìjọba ìbílẹ̀ Kaiama ní ìpínlè Kwara níbití ọpọlọpọ ènìyàn ti gbẹ̀mi mì.
Nínú àkọsílẹ̀ kan, ọgá agba ilé…
Ìkọlù Kwara: A kò Ní Gbà Fún Àwọn Ẹsinòkọkú-Ààrẹ Tinubu
Ààrẹ Bola Tinubu ti jẹjẹ pé orílẹ-èdè Naijiria kò ní tẹriba fún àwọn Ẹsinòkọkú alájàngbilà, wipe orílẹ-èdè yìí yóò daabobo àwọn èniyàn àti iyì wọn titi dòpin latari àwọn onipanle to fẹ fi tipatipa yì ẹsìn àwọn ènìyàn padà.
Ààrẹ…
Arábìnrin àkọ́kọ́ Anambra pè fún àyẹ̀wò ààrùn jẹjẹrẹ lásìkò
Ìyàwó Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Dókìtà Nonye Soludo ti túnbọ̀ rọ àwọn ènìyàn láti tẹramọ́ ìtọ́jú ìlera wọn, tí ó sì ń kìlọ̀ pé ààrùn jẹjẹrẹ ń gba ẹ̀mí jù, àti wípé àwọn ààrun ìgbà èwe tó ṣeé dènà…
Adarí alátakò South Africa sún sẹ́gbẹ̀ẹ́
Adarí Democratic Alliance (DA), John Steenhuisen ti kéde pé òun kò ní díje ìbò fún ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ lápapọ̀ ní oṣú kẹrin, ìpinnu tó fa ìṣiyèméjì sí ìṣọ̀kan ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè (GNU).
Steenhuisen, to ti ṣadari…
Nàìjíríà, Palestine fìdí àjọṣepọ̀ wọn múl̀ẹ
Mínísítà Nàìjíríà fún ọ̀rọ̀ òkèèrè, Aṣojú Yusuf Tuggar àti Aṣojú orílẹ̀-èdè Palestine sí Nàìjíríà, Muhannad Halmouri, ti gbà láti fì̀dí́ àjọṣepọ̀ ati ìfọwọ́wẹwọ́ aṣojú múl̀ẹ̀ láàrin orílẹ̀-èdè…