Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GÌN ÀTI ÀYÍKÁ

Àjọ Alámòjútó Àwùjọ Ti Parí Ètò Láti Pèsè Ilé Ìgbọ̀nsẹ̀ Lọ́pọ̀ Yanturu Lójúnà Àti…

Alákòóso Àgbà Fún Àjọ tí ó ń se àmójútó ìdàgbàsókè àwùjọ, Yusuf Kunle sọ pé àjọ náà ti parí ètò láti pèsè ilé ìgbọ̀nsẹ̀ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá jákè-jádò ìjọba ìbílẹ̀ tí ó wà ní Orílẹ̀-èdè…

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣe Ìdánilójú Iṣé Ìtèsíwájú Fún Àwọn Òṣìṣẹ́ Tó Ń Kólẹ̀.

Ìjọba àpapọ̀ ti ṣe ìlérí ìrànlọ́wọ́ àti ìtèsíwájú fún àwọn òṣìṣẹ́ to n kólẹ̀, wọn ní awọn o ni jẹ wọn lọwọ iṣé. Mínísítà fún ọ̀rọ̀ agbègbè ,Nyesom Wike lo sọ èyí di mímọ̀ mi ọjọ́ etí ni ìlú Abuja. Kpakol rọ àwọn òṣìṣẹ́ náà láti ní…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Katsina Fọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Tí Ọ̀rọ̀ Kàn Láti Mú Ìgbòòrò Bá Ètò…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Katsina ti sàlàyé pé òun yóò fi ọwọ́ sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àjọ àgbáyé tí o máa ń pèsè owó fún ìdàgbàsókè ètò ọ̀gbìn láti se ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àgbẹ̀ kí oúnjẹ le è sùwá bọ̀, tí yóò sì mú…

Ilé Ìtajà Ńlá Ọgbà Àti Àwọn Ọjà Míràn Ti Wà Ní Títìpa Ní Ìlú Èkó Látàrí…

Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ti pàṣẹ kí ilé ìtajà ńlá tí ó wà ní Ọgbà, Ikẹja, Ọjà Ajah, Etti Ọ̀sà, wà ní títìpa látàrí títàpásí òfin ìmọ́tótó àti ìdọ̀tí àyíká   Àkójọpọ̀ àwọn àjọ tí ó ń rí sí ètò…

Ètò Kárà-kátà Ti Bẹ̀rẹ̀ Padà Ní Pẹrẹwu Ní Ọjà Àgbáyé Alaba Ti Ìlú Èkó

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Eko, ní Gúsù Iwọ̀ oòrùn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti sí ọjà àgbáyé Alaba èyí tí ó ti wà ní títìpa tẹ́lẹ̀rí àti àwọn ọjà míràn ní àgbègbè Ọjọ, ní ọjọ́ Àbámẹ́ta tí kárà-kátà sì ti bẹ̀rẹ̀…
button