Browsing Category
ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN
Àjọ Kan Kọ́ Àwọn Obìnrin Ní Ẹ̀kọ́ Iṣẹ́ Oko Ìgbàlódé Àti Nípa Ìmọ̀ Ojú Ọjọ́
Àjọ International Centre for Environmental Health and Development (ICEHD) ti kọ́ Ọgọ́rùn ún àwọn àgbẹ obìnrin ní ìlú Abuja àti agbègbè rẹ̀ ni ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ ojú ọjọ́ àti iṣé oko nípa ti ìgbàlódé.
Nígbà ti ó n sọ̀rọ̀ níbi…
Ìyàwó Ààrẹ Gbé Òsùbà O káre Fún Ìpínlẹ̀ Anambra.
Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ṣẹ́nítọ̀ Oluremi Tinubu ti gbé Òsùbà o káre fún ìpínlẹ̀ Anambra fún iṣé takuntakun rẹ nípa ètò ọ̀gbìn àti fún ìrètí nlá nipa ohun ọ̀gbìn.
O sọ èyí di mímọ̀ lásìkò tí o ló fún ìpàdé pẹ̀lú ìyàwó àwọn Gómìnà…
Àjọ Ẹgbẹ́ Àgbẹ̀ Yan Tarnongu Bí Adarí Ti Ìpínlẹ̀ Benue
Àjọ ẹgbẹ àgbẹ̀-National Executive Council of the Federation of Agricultural Commodity Association of Nigeria (FACAN) ti buwọ́lu ìynsípò ọ̀gbẹ́ni Vitalis Tarnongu gẹ́gẹ́bí adarí rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Benue.
Ìynsípò rẹ̀ wáyé nínú lẹta ti…
Ẹgbẹ́ Tó N Sàkoso Ètò Nkọ ọ̀gbìn IITA Ṣe Ìdánilékòó Fún Aárùnlẹ́ẹ̀gbẹ́ta olè ọgọ́ta Àwon Ènìyàn Ni…
Ẹgbẹ́ IITA ní ìpínlẹ̀ Kano ti ṣe ètò ìdánilékòó nípa nkán ọ̀sìn fún àwọn ènìyàn Aárùnlẹ́ẹ̀gbẹ́ta olè ọgọ́ta àwọn ènìyàn ti ko pe ní Jigawa.
Nínú ifọrọwọrọ pẹlú ẹni tó ń wá ni ìṣàkóso Ìdánilékòó náà ni ojo ìṣẹgun, Ọ̀gbẹni Badamasi Muktar,…
Ìpínlẹ̀ Èkó Ṣetán Láti Ṣe Àṣeyọrí Èròngbà Ọdún Márún Fún Ohun Ọ̀gbìn:Kọmísọ́nà.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko àti ilé iṣé ìjọba tọ n mójú tó ètò ọ̀gbìn àti oúnjẹ sọ wí pé àwọn ti ṣetán láti mú èròngbà àwọn ṣe nípa ki kọ́ ilé ìtàjà tuntun láti mú ìdàgbàsókè ba ètò ọ̀gbìn.
Ìjọba ni àwọn ni ìdánilójú wí pé ètò ààbò oúnjẹ yóò mú…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kaduna Fẹ́ Mójútó Ọ̀gbìn Èso Gírèpù
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kaduna, Uba Sani ti fi dá àwọn àgbẹ̀ eléso Gírèpù lójú pé ìjọba òhun yóò pèsè èso ti wọn yóò gbìn, ẹ̀rọ fún oko Gírèpù, ẹ̀ko àti àtìlẹ́yìn to gbúnpon fún wọn fún ìmúgbóòrò ọ̀gbìn náà.
Gómìnà se ìlérí yìí nígbàtí ó se ìpàdé…
Ìpínlẹ̀ Ebonyi: Ẹgbẹ́ Labour Party Tí Rọ Gómìnà Nwifuru Láti Ṣe Iṣé Ọ̀gbìn.0
Akòwé fún ẹgbẹ́ LP Amòfin Luke Chibueze Adonwe tí rọ Gómìnà Francis Nwifuru láti ṣe iṣé àgbẹ̀ fún Ìdàgbàsókè ìpínlẹ̀ náà.
Adonwe sọ èyí di mímọ̀ ni ìlú Abakaliki, sọ wí pé pẹ̀lú ohun gbogbo ti àwọn ènìyàn n la koja báyìí nì Orílẹ̀-èdè…
Ìjọba ìpínlẹ̀ Edo Ṣe Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Obìnrin Oníṣẹ́ Ọ̀gbìn.
Àjọ tó ń mójú ìdàgbàsókè agbègbè ní ìjọba ìpínlẹ̀ Edo ti ṣe Ìrànlọ́wọ́ fún àwọn oníṣẹ́ ọ̀gbìn tó jẹ Obìnrin ni ìjọba ìbílẹ̀ Uhumwode nipa Pin Pin àwọn ohun tí yóò mú Ìdàgbàsókè ba àwọn èrè oko wọn.
Awọn ǹkan ọ̀gbìn bi, àmúewébẹ̀ dàgbà,ogún…