Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ

This is a category for entertainment news

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Tẹ́lẹ̀rí Olusẹgun Ọbasanjọ Se Ayẹyẹ Ọjọ́ Ìbí Ọdún…

 Ààrẹ Orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀rí, Olusẹgun Ọbasanjọ ti ké sí àwọn ọmọ Naijiria, papàá jùlọ àwọn ọ̀dọ́ láti ko ipa tí ó làmì-laaka èyí tí yóò mú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dé ilẹ̀ ìlérí   Ọbasanjọ pàrọwà sí…

Ààrẹ Tinubu ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú ògbóhùntarìjgì òṣèré Nkem Owoh ní ààdọ́rin ọdún

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kí ògbóhùntarìjgì òṣèré Nollywood, apanilẹ́ẹ́rín,akọrin tí ó tún jẹ́ olukọ̀ọ orin, Ọ̀gbẹ́ni Nkem Owoh, MON, bí ó ṣe ń ṣe ọjọ́ ìbí ààdọ́rin ọdún rẹ̀. Lori ajọyọ naa, aarẹ Tinubu gboriyin…

Aya Ààrẹ Nàìjíríà Pèsè Mílíọ̀nù Àádọ́talélọ̀dúnrún Náírà Fún Ìpèsè Eré Orí Ìtàgé

Aya Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sénétọ̀ Oluremi Tinubu ti gbé Mílíọ̀nù Àádọ́talélọ̀dúnrún Náírà kalẹ̀ fún Ìpèsè eré orí ìtàgé láti bu ẹwà kún àṣà àti ìṣe ìpínlẹ̀ Kwara látàrí irin isẹ́ àwòmáleèlọ tó bá ìgbà mu ti Kwara State’s…

Ìjákulẹ̀ Dé Bámi Lórí Ètò Ẹ̀kọ́ Látàrí Ìsàfẹ́kù Owó Péréte- Ice Prince Sàlàyé…

Gbajúgbajà akọrin Panshak Zamani, tí gbogbo ayé mọ̀ sí Ice Prince ti sàlàyé ìpèníjà àti àwọn ìsòro tí ó kojú ninu ìgbé ayé rẹ̀ látàrí ìpàdánù àwọn òbí rẹ ati bí àwọn ìpèníjà náà se jẹ́ atọ́nà èyí…
button