Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ Tẹ̀síwájú Láti Jẹ́ Olóòtọ́ọ́ Àti Nínú Iṣẹ́ Àsekára- Olurẹmi Tinubu Pàrọwà Sí Àwọn…

Aya Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjírìà, Olurẹmi Tinubu ti pàrọwà sí àwọn ọ̀dọ́ láti tẹ̀síwájú nínú ojúse wọn fún síṣe iṣẹ́ àsekára àti jíjẹ́ olóòtọ́ọ́ láti jẹ́ ènìyàn rere tí yóò wúlò fún àwùjọ Ó…

Yunifásitì Ìlú Ilọrin Fún Ènìyàn Mẹ́rìndínlógún Tí Ó Peregedé Jùlọ Ní Àmì Ẹ̀yẹ

Ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́jáde ti Yunifásitì tí ó fi ìlú Ìlọrin Se Ibùjókòó ti fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́jáde mẹ́rìndínlógún tí ó peregedé jùlọ nínú àwọn akẹ́ẹ̀kọ́jáde ti ọdún 2024 fún ìlàmìlaaka àti iṣẹ́ takun-takun tí wọ́n…

N Ó Se Ìgbélárugẹ Fún Ìdàgbàsókè Olú Ìlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà- Abbas Jẹ́jẹ̀ẹ́

Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asoju Sòfin Nàìjíríà, Ọ̀gbẹ́ni Tajudeeen Abbas ti fi ọ̀rọ̀ léde wípé Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nílò tírílíọ̀nù mẹ́ta dọ́là láti pèsè àwọn ohun amáyédẹrùn ní gbèdéke ọgbọ̀n ọdún síwájú…

Ẹ̀kọ́ Ilé Tí Ó Yè Kooro Jẹ́ Ọ̀nà Àbáyọ Sí Ìsòro Ìwà Jìbìtì Orí Ẹ̀rọ Ayélujára-…

Wọ́n ti gba àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà níyànjú láti se àmójútó ẹ̀kọ́ ilé ati àwọn ìwà tí ó bá àwùjọ mu láti gbógunti ìwà ìbàjẹ́ láwùjọ Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara tí ó tún jẹ́ alága àpapọ̀ fún…

Soludo Pè Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Láti Sàgbékalẹ̀ Ètò Ọrọ̀ Ajé Èyí Tí Yóò Fìdí Múlẹ̀…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Charles Soludo ti ké sí tolórí-tẹlẹ́mù láti fọwọ́sowọ́pọ̀ fún ìsàgbékalẹ̀ ètò ọrọ̀ ajé tí ó múná dóko Ó pe ìpè náà níbi àpérò kan tí ó wáyé ní ìlú Abuja…
button