Gómìnà Ìpínlẹ̀ Sokoto Jẹ́jẹ̀ẹ́ Láti Pèsè Àwọn Ohun Amáyédẹrùn
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Sokoto, Ahmed Aliyu ti fi àrídájú hàn sí àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ náà láti se àlékún ìpèsè àwọn ohun amáyédẹrùn ní ọdún 2025, o fi ìfarajì rẹ̀ léde láti sọ ayé di gbẹdẹmukẹ fún àwọn eniyan rẹ…