Orilẹ̀-ède Eritrea Darapọ̀ Mọ́ Àjọ East Africa Bloc Lẹ́yìn Ọdún Mẹ́rìndínlógún
Orílẹ̀-èdè Eritrea ti darapọ̀ mọ́ àjọ East Africa Bloc ti Intergovernmental Authority on Development, IGAD lẹ́yìn tó ti kúrò nínú ẹgbẹ́ láti ọdún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn.
Mínísítà ọ̀rọ̀ nípa Ìròyìn,Yemane Meskel ló sọ…