Take a fresh look at your lifestyle.

Olórí Ìjọba Ológun Ní Orílẹ̀-èdè Sudan Pààrọ̀ Gómìnà Méjì

0 111

Olórí Ìjọba Ológun Ní Orílẹ̀-èdè Sudan Pààrọ̀ Gómìnà Méjì

Olórí Ìjọba Ológun , Abdel al-Burhan ní Orílẹ̀-èdè Sudan ti pààrọ̀ Gómìnà Méjì

Eléyìí ri be bi ija ti n gbóná girigiri ni olú ilu-Khartoum ati agbegbe míràn laarin Ologun ati iko paramilitary Rapid Support Forces, RSF. Awọn mejeji woya ija, wọn dìtẹ gba ijoba ni osu Kewa odun
2021, sugbon awon mejeji bayii ni jaja gbara lati jẹ Olori patapata.

Ogagun Burhan le Gómìnà ti Ariwa Kordofan, Fadlallah al-Tom ati ti ipinle Sennar, Al-Alim al-Nour danu. O fi aropo miran sí. Ko so ìdì to fi ṣe bẹ bi iroyin se sọ.

Apakan ti Ariwa Kordofan lo ti n dojú kọ ogun lile, kò sì sí ìjà kankan ni ti ipinle Sennar.

O kéré tán, ènìyàn bí ẹgbẹ̀rún tí ko mo nipa ogun lo ti gbemi mi ti ènìyàn to din die ni egberun merin sí ti fara pa ni igba ti edeaiyede náà ti bẹ silẹ ni ọjọ karun din logun , oṣù kẹrin.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.