Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Putin Yóò Gba Àlejò Àjọ Alálàfíà Láti Ilẹ̀ Adúláwọ̀

0 102

Ààrẹ Putin Yóò Gba Àlejò Àjọ Alálàfíà Láti Ilẹ̀ Adúláwọ̀

Ààrẹ orílẹ̀-èdè South Africa, Cyril Ramaphosa, àti ojúgbà rẹ̀, Vladimir Putin ti bá ara wọn sọ̀rọ̀ lórí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ lórí ọ̀rọ̀ ètò àlàáfíà ti àwọn adarí mẹ́fà láti ilẹ Adúláwọ̀ ń bọ̀ wá ṣe nípa orílẹ̀-èdè Russia àti Ukraine.

Ni ọjọ isegun, awọn adari ile adulawo ti oro kan se ìpàdé nipa bi àawọ̀ ile náà yóò ṣe dopin.
Awọn orilẹ-ede ile adulawo to n se eyi ni: Egypt, Senegal, Uganda, ati Senegal.

Bí Iroyin se sọ láti ẹka ti ọdọ ààrẹ sọ wipe won yóò ní anfani lati lọ ni aarin oṣù Kẹfà.

Awọn adari naa yóò se ìpàdé po pẹlú aare méjèèjì Putin ati Volodymyr Zelensky bí alaafia yóò ṣe joba ni agbegbe naa ti ko ní sí iro ibọn keu keu mo.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.