Take a fresh look at your lifestyle.

Ọrọ̀ Ajé Àgbáyé Wà Ní Ipò Tó Léwu- Báńkì Àgbáyé Kìlọ̀

0 139

 

Àtẹ̀jáde tuntun láti ọ̀dọ̀ báǹkì àgbáyé sọ pé owó èlé ìdókòwò àti ogun ìlú Russia àti Ukraine ti fa kí ọrọ̀ ajé àgbáyé dẹnu kọlẹ̀.

Ìròyìn tó pe bí oro ajé àgbáyé ṣe gbera so lọ sí ọ ìpín meta o le die ni ti ogorun ni odun to koja, yóò lo sí ìpín meji o le die ni ti ogorun ni odun 2023.

Onimo àgbà ètò orò ajé àgbáyé, Indermit Gill sọ pé idagbasoke eyi ló buru jai ju ni nnkan bi Àádọta odun seyin.

“Ọrọ̀ ajé àgbáyé wà ní ipò tó léwu,”

Gill so bẹẹ.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.