Take a fresh look at your lifestyle.

Aya Ààrẹ Nàìjíríà Pèsè Mílíọ̀nù Àádọ́talélọ̀dúnrún Náírà Fún Ìpèsè Eré Orí Ìtàgé

Aya Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sénétọ̀ Oluremi Tinubu ti gbé Mílíọ̀nù Àádọ́talélọ̀dúnrún Náírà kalẹ̀ fún Ìpèsè eré orí ìtàgé láti bu ẹwà kún àṣà àti ìṣe ìpínlẹ̀ Kwara látàrí irin isẹ́ àwòmáleèlọ tó bá ìgbà mu ti Kwara State’s…

Alága Gbogbogbò Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Gba Ọmọ Ẹgbẹ́ Tuntun Ogójì Ẹgbẹ̀rún Wọlé Ní Ìpínlẹ̀ Katsina

Alága Gbogbogbò Ẹgbẹ́ Òsèlú APC, All Progressives Congress, Dokita Abdullahi Ganduje, ti gba ọmọ ẹgbẹ́ tuntun tó tó Ogójì Ẹgbẹ̀rún ti wọn sá kúrò látì ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹgbẹ́ òsèlú ní ìpínlẹ̀ Katsina wọlé sínú Ẹgbẹ́ Òsèlú APC. Ganduje…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kaduna, Uba Sani ti fi dá àwọn àgbẹ̀ eléso Gírèpù lójú pé ìjọba òhun yóò pèsè èso ti wọn yóò gbìn, ẹ̀rọ fún oko Gírèpù, ẹ̀ko àti àtìlẹ́yìn to gbúnpon fún wọn fún ìmúgbóòrò ọ̀gbìn náà. Gómìnà se ìlérí yìí nígbàtí…

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó Pé Gómìnà Sanwo-Olu Láti Fọwọ́ Ọ̀kúnkúndùn Mú Ọ̀rọ̀ Àwọn Ajínri Àti…

Pẹ̀lú ìgbésẹ̀ láti fi dáàbò bo àwọn nǹkan ìní ìjọba àti ààbò àwọn ará ìlú lójú pópó, Ilé Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó ti rọ Gómìnà Sanwo-Olu láti pàṣẹ fífi ọwọ́ ṣìnkún òfin mú àwọn olè akólè lójú pópó tí kò bá òfin mu. Ilé Aṣòfin náà…

Olùdarí Ilé Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó Ṣe Ìlérí Títẹ̀lé Ìlànà Ìṣàkóso Rere Àti Òdodo

Olùdarí Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó, Aṣòfin Mojisola Meranda fi múlẹ̀ ní ọjọ́ Ẹtì, (Friday) tí í ṣe ọjọ́ àkọ́kọ́, tí yóò dárí Ìgbìmọ̀ Aṣòfin náà gẹ́gẹ́ bí Olùdarí Ilé náà lẹ́yìn tí wọ́n ti yọ, olùdarí àná, pé òun yóò ṣe ìjọba…
button